Eks 9:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori nisisiyi, emi iba nà ọwọ́ mi, ki emi ki o le fi ajakalẹ-àrun lù ọ, ati awọn enia rẹ; a ba si ti ke ọ kuro lori ilẹ.

Eks 9

Eks 9:12-19