Eks 8:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni awọn alalupayida wi fun Farao pe, Ika Ọlọrun li eyi: ṣugbọn àiya Farao le, kò si fetisi ti wọn; bi OLUWA ti wi.

Eks 8

Eks 8:10-23