Eks 7:24-25 Yorùbá Bibeli (YCE)

24. Gbogbo awọn ara Egipti si wàlẹ yi odò na ká fun omi mimu; nitoriti nwọn kò le mu ninu omi na.

25. Ọjọ́ meje si pé, lẹhin igbati OLUWA lù odò na.

Eks 7