Eks 5:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mose si pada tọ̀ OLUWA lọ, o si wi fun u pe, OLUWA, ẽtiṣe ti o fi ṣe buburu si awọn enia yi bẹ̃? ẽtiṣe ti o fi rán mi?

Eks 5

Eks 5:13-23