Eks 5:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn olori awọn ọmọ Israeli si ri pe, ọ̀ran wọn kò li oju, lẹhin igbati a wipe, Ẹ ki o dinkù ninu iye briki nyin ojojumọ́.

Eks 5

Eks 5:12-23