Eks 40:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE) OLUWA si sọ fun Mose pe, Li ọjọ́ kini oṣù kini ni ki iwọ ki o gbé ibugbé agọ́ na ró.