Eks 39:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si ṣiṣẹ́ okuta oniki ti a tò sinu oju-ìde wurà, ti a fin bi ifin èdidi-àmi ti a fin orukọ awọn ọmọ Israeli si.

Eks 39

Eks 39:1-13