Eks 39:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe ẹ̀wu-efodi na ti wurà, ati aṣọ-alaró, ati elesè-àluko, ati ododó, ati ọ̀gbọ olokùn wiwẹ.

Eks 39

Eks 39:1-3