Eks 37:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. BESALELI si fi igi ṣittimu ṣe apoti na: igbọnwọ meji on àbọ ni gigùn rẹ̀, ati igbọnwọ kan on àbọ ni ibú rẹ̀, igbọnwọ kan on àbọ si ni giga rẹ̀:

2. O si fi kìki wurà bò o ninu ati lode, o si ṣe igbáti wurà si i yiká.

Eks 37