Eks 35:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

MOSE si pè apejọ gbogbo ijọ awọn ọmọ Israeli, o si wi fun wọn pe, Wọnyi li ọ̀rọ ti OLUWA palaṣẹ pe, ki ẹnyin ki o ṣe wọn.

Eks 35

Eks 35:1-3