Eks 32:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati Aaroni si ri i, o tẹ́ pẹpẹ kan niwaju rẹ̀; Aaroni si kede, o si wipe, Ọla li ajọ fun OLUWA.

Eks 32

Eks 32:3-13