Eks 3:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ nisisiyi, kiyesi i, igbe awọn ọmọ Israeli dé ọdọ mi; emi si ti ri pẹlu, wahala ti awọn ọba Egipti nwahala wọn.

Eks 3

Eks 3:1-13