Eks 3:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mose si wi fun Ọlọrun pe, Tali emi, ti emi o fi tọ̀ Farao lọ, ati ti emi o fi le mú awọn ọmọ Israeli jade lati Egipti wá?

Eks 3

Eks 3:1-19