Eks 28:40 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ o si dá ẹ̀wu-awọtẹlẹ fun awọn ọmọ Aaroni, iwọ o si dá ọjá-amure fun wọn, iwọ o si dá fila fun wọn, fun ogo ati fun ọṣọ́.

Eks 28

Eks 28:34-41