Eks 26:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ o si ṣe aṣọ-tita irun ewurẹ, lati ṣe ibori sori agọ́ na: aṣọ-tita mọkanla ni iwọ o ṣe e.

Eks 26

Eks 26:6-17