Eks 24:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ogo OLUWA si sọkalẹ sori òke Sinai, awọsanma na si bò o mọlẹ ni ijọ́ mẹfa: ni ijọ́ keje o ké si Mose lati ãrin awọsanma wá.

Eks 24

Eks 24:6-18