Eks 23:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi iwọ ba bá akọmalu tabi kẹtẹkẹtẹ ọtá rẹ ti o ṣina, ki iwọ ki o mú u pada fun u wá nitõtọ.

Eks 23

Eks 23:1-5