Eks 23:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati ajọ ikore, akọ́so iṣẹ rẹ, ti iwọ gbìn li oko rẹ: ati ajọ ikore oko, li opin ọdún, nigbati iwọ ba ṣe ikore iṣẹ oko rẹ tán.

Eks 23

Eks 23:11-20