Eks 23:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati li ohun gbogbo ti mo wi fun nyin, ẹ ma ṣọra: ki ẹ má si ṣe iranti orukọ oriṣakoriṣa ki a má ṣe gbọ́ ọ li ẹnu nyin.

Eks 23

Eks 23:4-14