Eks 22:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi ẹnikan ba fi owo tabi ohunèlo fun ẹnikeji rẹ̀ pamọ́; ti a ji i ni ile ọkunrin na; bi a ba mu olè na, ki o san a ni meji.

Eks 22

Eks 22:6-16