Eks 22:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi enia ba si yá ohun kan lọwọ ẹnikeji rẹ̀, ti o si farapa, tabi ti o kú, ti olohun kò si nibẹ̀, on o san ẹsan nitõtọ.

Eks 22

Eks 22:6-19