Eks 21:33 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi ẹnikan ba ṣi ihò silẹ, tabi bi ọkunrin kan ba si wà ihò silẹ, ti kò si bò o, ti akọmalu tabi kẹtẹkẹtẹ ba bọ́ sinu rẹ̀;

Eks 21

Eks 21:27-35