Eks 21:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn bi enia ba ṣìka si aladugbo rẹ̀, lati fi ẹ̀tan pa a; ki iwọ ki o tilẹ mú u lati ibi pẹpẹ mi lọ, ki o le kú.

Eks 21

Eks 21:12-19