Eks 20:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

OLUWA si wi fun Mose pe, Bayi ni ki iwọ ki o wi fun awọn ọmọ Israeli pe, Ẹnyin ri bi emi ti bá nyin sọ̀rọ lati ọrun wá.

Eks 20

Eks 20:13-26