Eks 20:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo awọn enia na si ri ãrá na, ati mànamána na, ati ohùn ipè na, nwọn ri oke na nṣe ẽfi: nigbati awọn enia si ri i, nwọn ṣí, nwọn duro li òkere rére.

Eks 20

Eks 20:12-26