Eks 20:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. ỌLỌRUN si sọ gbogbo ọ̀rọ wọnyi pe,

2. Emi li OLUWA Ọlọrun rẹ, ti o mú ọ jade lati ilẹ Egipti, lati oko-ẹrú jade wá.

3. Iwọ kò gbọdọ lí Ọlọrun miran pẹlu mi.

Eks 20