Eks 2:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana li arabinrin rẹ̀ wi fun ọmọbinrin Farao pe, Emi ka lọ ipè alagbatọ kan fun ọ wá ninu awọn obinrin Heberu, ki o tọ́ ọmọ na fun ọ?

Eks 2

Eks 2:3-17