Eks 2:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọlọrun si gbọ́ irora wọn, Ọlọrun si ranti majẹmu rẹ̀ pẹlu Abrahamu, pẹlu Isaaki, ati pẹlu Jakobu.

Eks 2

Eks 2:21-25