Eks 2:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si wipe, Ara Egipti kan li o gbà wa lọwọ awọn oluṣọ-agutan, o si pọn omi to fun wa pẹlu, o si fi fun agbo-ẹran.

Eks 2

Eks 2:10-21