Eks 2:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ alufa Midiani li ọmọbinrin meje, nwọn si wá, nwọn pọn omi, nwọn si kún ọkọ̀ imumi lati fi omi fun agbo-ẹran baba wọn.

Eks 2

Eks 2:7-17