Eks 19:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo awọn enia na si jùmọ dahùn, nwọn si wipe, Ohun gbogbo ti OLUWA wi li awa o ṣe. Mose si mú ọ̀rọ awọn enia pada tọ̀ OLUWA lọ.

Eks 19

Eks 19:3-11