Eks 19:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnyin o si ma jẹ́ ijọba alufa fun mi, ati orilẹ-ède mimọ́. Wọnyi li ọ̀rọ ti iwọ o sọ fun awọn ọmọ Israeli.

Eks 19

Eks 19:1-10