Eks 19:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn sá ti ṣi kuro ni Refidimu, nwọn si wá si ijù Sinai, nwọn si dó si ijù na; nibẹ̀ ni Israeli si dó si niwaju oke na.

Eks 19

Eks 19:1-4