Eks 19:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

OLUWA si wi fun Mose pe, Tọ̀ awọn enia yi lọ, ki o si yà wọn simimọ́ li oni ati li ọla, ki nwọn ki o si fọ̀ asọ wọn.

Eks 19

Eks 19:9-13