Eks 18:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mose si jade lọ ipade ana rẹ̀, o si tẹriba, o si fi ẹnu kò o li ẹnu, nwọn si bére alafia ara wọn; nwọn si wọ̀ inu agọ́.

Eks 18

Eks 18:1-13