Eks 18:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mose si yàn awọn enia ti o to ninu gbogbo Israeli, o si fi wọn ṣe olori awọn enia, olori ẹgbẹgbẹrun, olori ọrọrún, olori arãdọta, olori mẹwamẹwa.

Eks 18

Eks 18:18-27