Eks 18:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki o si ma kọ́ wọn ni ìlana ati ofin wọnni, ki o si ma fi ọ̀na ti nwọn o ma rìn hàn fun wọn ati iṣẹ ti nwọn o ma ṣe.

Eks 18

Eks 18:11-26