Eks 18:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jetro si wipe, Olubukún li OLUWA, ẹniti o gbà nyin là lọwọ awọn ara Egipti, ati lọwọ Farao, ẹniti o gbà awọn enia là lọwọ awọn ara Egipti.

Eks 18

Eks 18:1-20