Eks 16:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe ni ijọ́ kẹfa, nwọn kó ìwọn onjẹ ẹrinmeji, omeri meji fun ẹni kọkan: gbogbo awọn olori ijọ na si wá nwọn sọ fun Mose.

Eks 16

Eks 16:18-29