Eks 16:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe li aṣalẹ ni aparò fò dé, nwọn si bò ibudó mọlẹ; ati li owurọ̀ ìri si sẹ̀ yi gbogbo ibudó na ká.

Eks 16

Eks 16:8-22