Eks 15:3-5 Yorùbá Bibeli (YCE)

3. Ologun li OLUWA; OLUWA li orukọ rẹ̀.

4. Kẹkẹ́ Farao ati ogun rẹ̀ li o mu wọ̀ inu okun: awọn ãyo olori ogun rẹ̀ li o si rì ninu Okun Pupa.

5. Ibú bò wọn mọlẹ: nwọn rì si isalẹ bi okuta.

Eks 15