Eks 15:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati nwọn dé Mara, nwọn ko le mu ninu omi Mara, nitoriti o korò; nitorina li a ṣe sọ orukọ rẹ̀ ni Mara.

Eks 15

Eks 15:22-24