Eks 15:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Miriamu si da wọn li ohùn pe, Ẹ kọrin si OLUWA nitoriti o pọ̀ li ogo; ẹṣin ati ẹlẹṣin on li o bì ṣubu sinu okun.

Eks 15

Eks 15:11-23