Eks 15:12-14 Yorùbá Bibeli (YCE)

12. Iwọ nà ọwọ́ ọtún rẹ, ilẹ gbe wọn mì.

13. Ninu ãnu rẹ ni iwọ fi ṣe amọ̀na awọn enia na ti iwọ ti rapada: iwọ si nfi agbara rẹ tọ́ wọn lọ si ibujoko mimọ́ rẹ.

14. Awọn enia gbọ́, nwọn warìri; ikãnu si mú awọn olugbe Palestina.

Eks 15