Eks 12:32 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹ si mú agbo nyin ati ọwọ́-ẹran nyin, bi ẹ ti wi, ki ẹ si ma lọ; ki ẹ si sure fun mi pẹlu.

Eks 12

Eks 12:30-36