Eks 12:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹ kò si gbọdọ jẹ ki nkan ki o kù silẹ ninu rẹ̀ dé ojumọ́; eyiti o ba si kù di ijọ́ keji on ni ki ẹnyin ki o daná sun.

Eks 12

Eks 12:2-12