Eks 10:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Farao ranṣẹ pè Mose ati Aaroni kánkan; o si wipe, Emi ti ṣẹ̀ si OLUWA Ọlọrun nyin, ati si nyin.

Eks 10

Eks 10:9-18