Eks 1:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọmọ Israeli si bisi i, nwọn si pọ̀si i gidigidi, nwọn si rẹ̀, nwọn si di alagbara nla jọjọ; ilẹ na si kún fun wọn.

Eks 1

Eks 1:1-16