Eks 1:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina ni nwọn ṣe yàn akoniṣiṣẹ le wọn, lati fi iṣẹ wọn pọ́n wọn loju. Nwọn si kọ́ ilu iṣura fun Farao, Pitomu ati Ramesesi.

Eks 1

Eks 1:1-18