Ẹk. Jer 4:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. BAWO ni wura ṣe di baibai! bawo ni wura didara julọ ṣe pada! okuta ibi-mimọ́ li a tuka ni gbogbo ori ita.

2. Awọn ọmọ iyebiye Sioni, ti o niye lori bi wura didara, bawo li a ṣe kà wọn si bi ikoko amọ̀, iṣẹ ọwọ alamọ̀!

Ẹk. Jer 4